Orin Sólómónì 5:7 BMY

7 Àwọn olùṣọ́ tí ń ṣọ ìlú rí mibí wọ́n ti ṣe ń rìn yí ìlú ká.Wọ́n nà mí, wọ́n ṣá mi lọ́gbẹ́;wọ́n gba ìborùn mi lọ́wọ́ mi.Àwọn olùṣọ́ tí ń ṣọ́ odi!

Ka pipe ipin Orin Sólómónì 5

Wo Orin Sólómónì 5:7 ni o tọ