Sekaráyà 1:9 BMY

9 Nígbà náà ni mo wí pé, “Kí ni wọ̀nyí Olúwa mi?”Ańgẹ́lì tí ń ba mi sọ̀rọ̀ sì wí fún mi pé, “Èmi ó fi ohun tí wọ̀nyí jẹ́ hàn ọ́.”

Ka pipe ipin Sekaráyà 1

Wo Sekaráyà 1:9 ni o tọ