Sekaráyà 3:10 BMY

10 “ ‘Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí pé, ní ọjọ́ náà ni olúkúlùkù yóò pe ẹnìkejì láti jókòó rẹ̀ sábẹ́ igi àjàrà àti sábẹ́ igi ọ̀pọ̀tọ́.’ ”

Ka pipe ipin Sekaráyà 3

Wo Sekaráyà 3:10 ni o tọ