Sekaráyà 6:15 BMY

15 Àwọn tí ó jìnnà réré yóò wá láti kọ́ tẹ́ḿpìlì Olúwa, ẹ̀yiń o sì mọ̀ pé, Olúwa àwọn ọmọ-ogun ti rán mi sí yín. Yóò sì rí bẹ́ẹ̀ bí ẹ̀yín o bá gbà ohùn Olúwa, Ọlọ́run yín gbọ́ nítootọ́.”

Ka pipe ipin Sekaráyà 6

Wo Sekaráyà 6:15 ni o tọ