Sekaráyà 7:9 BMY

9 “Báyìí ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí pé: ‘Ṣe ìdájọ́ òtítọ́, kí ẹ sì ṣe àánú àti iyọ́nú olúkúlùkù sí arákùnrin rẹ̀.

Ka pipe ipin Sekaráyà 7

Wo Sekaráyà 7:9 ni o tọ