Sekaráyà 8:16 BMY

16 Wọ̀nyí ni nǹkan tí ẹ̀yin ó ṣe: Ẹ ṣọ̀rọ̀ òtítọ́, olúkúlúkù sí ẹnikejì rẹ̀; ṣe ìdájọ́ tòótọ́ àti àlàáfíà ní àwọn ibodè yín.

Ka pipe ipin Sekaráyà 8

Wo Sekaráyà 8:16 ni o tọ