1 Pétérù 4:15 BMY

15 Ṣùgbọ́n ẹ má jẹ́ kí ẹnikẹ́ni nínú yín jìyà bí àpànìyàn, tàbí bí olè, tàbí bí olùṣé búburú, tàbí bí ẹni tí ń tọjúbọ̀ ọ̀ràn ẹlòmíràn.

Ka pipe ipin 1 Pétérù 4

Wo 1 Pétérù 4:15 ni o tọ