1 Pétérù 4:6 BMY

6 Nítorí èyí ní a ṣá ṣe wàásù ìyìn rere fún àwọn òkú, kí a lè ṣe ìdájọ́ wọn gẹ́gẹ́ bí ènìyàn nípa ti ara, ṣùgbọ́n kí wọ́n lè wà láàyè si Ọlọ́run nípa tí Ẹ̀mí.

Ka pipe ipin 1 Pétérù 4

Wo 1 Pétérù 4:6 ni o tọ