1 Pétérù 4:7 BMY

7 Ṣùgbọ́n òpin ohun gbogbo kù sí dẹ̀dẹ̀; nítorí náà kí ẹ̀yin wà ní àìrékọjá, kí ẹ sì máa sọra nínú àdúrà.

Ka pipe ipin 1 Pétérù 4

Wo 1 Pétérù 4:7 ni o tọ