2 Kọ́ríńtì 12:13 BMY

13 Nítorí nínú kín ni ohun tí ẹ̀yin ṣe rẹ̀yìn sí ìjọ mìíràn, bí kò ṣe ní ti pé èmi fúnra mi kó jẹ́ oníyọnú fún yín? Ẹ dárí àṣìṣe yìí jì mí.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 12

Wo 2 Kọ́ríńtì 12:13 ni o tọ