2 Kọ́ríńtì 12:3 BMY

3 Bẹ́ẹ̀ ni èmi mọ irú ọkùnrin bẹ́ẹ̀, yálà ní ara ni, tàbí kúrò nínú ara ni, èmi kò mọ̀: Ọlọ́run mọ̀.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 12

Wo 2 Kọ́ríńtì 12:3 ni o tọ