2 Kọ́ríńtì 3:2 BMY

2 Ẹ̀yin fúnara yín ni ìwé ìyìn wa, tí a ti kọ sí yín ní ọkàn, ti gbogbo ènìyàn mọ̀, tí wọ́n sì ń kà.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 3

Wo 2 Kọ́ríńtì 3:2 ni o tọ