2 Kọ́ríńtì 3:3 BMY

3 Ẹ̀yin sì ń fi hàn pé ìwé tí a gbà sílẹ̀ láti ọ̀dọ̀ Kírísítì ni yín, kì í ṣe èyí tí a si fi jẹ́lú kọ, bí kò sẹ Ẹ̀mí Ọlọ́run alààyè; kì í ṣe nínú wàláà okútà bí kò ṣe nínú wàláà ọkàn ènìyàn.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 3

Wo 2 Kọ́ríńtì 3:3 ni o tọ