2 Kọ́ríńtì 8:22 BMY

22 Àwa sì ti rán arákùnrin wa pẹ̀lú wọn, ẹni tí àwa rí dájú nígbà púpọ̀ pé ó ní ìtara nínú ohun púpọ̀, ṣùgbọ́n ní isínsnyìí ni ìtara rẹ̀ túbọ pọ̀ sí i nípa ìfọkàntàn ńlá tí ó ní sí yín.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 8

Wo 2 Kọ́ríńtì 8:22 ni o tọ