2 Kọ́ríńtì 8:23 BMY

23 Bí ẹnikẹ́ni bá béèrè ẹni tí Títù jẹ́, ẹlẹ́gbẹ́ àti olùbáṣiṣẹ́ mi ni, nítorí yín; tàbí ní ti àwọn arákùnrin wa ni ẹnikẹ́ni ń bèèrè, ìránṣẹ́ ìjọ ni wọ́n jẹ́, àti ògo Kírísítì.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 8

Wo 2 Kọ́ríńtì 8:23 ni o tọ