2 Kọ́ríńtì 9:11 BMY

11 Bẹ́ẹ̀ ni a ó sọ yín di ọlọ́rọ̀ nínú ohun gbogbo, fún ìlawọ́ yín gbogbo tí ń ṣiṣẹ́ ọpẹ́ sí Ọlọ́run nípa wa.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 9

Wo 2 Kọ́ríńtì 9:11 ni o tọ