2 Kọ́ríńtì 9:8 BMY

8 Ọlọ́run sì lè mú kí gbogbo oore ọ̀fẹ́ máa bí sí i fún yín; kí ẹ̀yin tí ó ní ànító ohun gbogbo, nígbà gbogbo, lè máa pọ̀ sí i ní iṣẹ́ rere gbogbo.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 9

Wo 2 Kọ́ríńtì 9:8 ni o tọ