Éfésù 1:15 BMY

15 Nítorí ìdí èyí, nígbà tí mo ti gbúro ìgbàgbọ́ ti ń bẹ láàárin yín nínú Jésù Olúwa, àti ìfẹ́ yín sí gbogbo àwọn ènìyàn mímọ́.

Ka pipe ipin Éfésù 1

Wo Éfésù 1:15 ni o tọ