Éfésù 1:9 BMY

9 Ó ti sọ ohun ìjìnlẹ̀ ìfẹ́ rẹ̀ di mímọ̀ fún wa, gẹ́gẹ́ bí idùnnù rere rẹ̀, èyí ti o pinnu nínú Kírísítì,

Ka pipe ipin Éfésù 1

Wo Éfésù 1:9 ni o tọ