Éfésù 3:8 BMY

8 Fún èmi tí o kéré jùlọ nínú gbogbo àwọn ènìyàn mímọ́, ní a fi oore ọ̀fẹ́ yìí fún, láti wàásù àwámárídi ọ̀rọ̀ Kírísítì fún àwọn aláìkọlà;

Ka pipe ipin Éfésù 3

Wo Éfésù 3:8 ni o tọ