Éfésù 4:1 BMY

1 Nítorí náà, èmi òǹdè nínú Olúwa ń bẹ̀ yín pé kí ẹ̀yin máa gbé ìgbé ayé tí ó yẹ sí ìpè tí a pè yín sí.

Ka pipe ipin Éfésù 4

Wo Éfésù 4:1 ni o tọ