Éfésù 4:19 BMY

19 Àwọn ẹni tí ọkàn wọn le rékọjá, tí wọ́n sì ti fi ara wọn fún wọ̀bìà, láti máa fi ìwọ́ra ṣiṣẹ́ ìwà èérí gbogbo.

Ka pipe ipin Éfésù 4

Wo Éfésù 4:19 ni o tọ