Jákọ́bù 3:10 BMY

10 Láti ẹnu kan náà ni ìyìn àti èébú ti ń jáde. Ẹ̀yin ará mi, nǹkan wọ̀nyí kò yẹ kí ó rí bẹ́ẹ̀.

Ka pipe ipin Jákọ́bù 3

Wo Jákọ́bù 3:10 ni o tọ