Jákọ́bù 3:2 BMY

2 Nitorí nínú ohun púpọ̀ ni gbogbo wa ń ṣe àṣìse. Bí ẹni kan kò bá sì sì ṣe nínú ọ̀rọ̀, òun náà ni ẹni pípé, òun ni ó sì le kó gbogbo ara ní ìjánu.

Ka pipe ipin Jákọ́bù 3

Wo Jákọ́bù 3:2 ni o tọ