Jákọ́bù 3:7 BMY

7 Nítorí olúkúlùkù ẹ̀dá ẹranko, àti ti ẹyẹ, àti ti ejò, àti ti ohun tí ó ń bẹ ní òkun, ni à ń tù lójú, tí a sì ti tù lójú láti ọwọ́ ẹ̀dá ènìyàn wá.

Ka pipe ipin Jákọ́bù 3

Wo Jákọ́bù 3:7 ni o tọ