Jákọ́bù 4:12 BMY

12 Aṣòfin àti onídàájọ́ kan ṣoṣo ní ó ń bẹ, àní ẹni tí ó lè gbà là tí ó sì le parun, Ṣùgbọ́n ta ni ìwọ tí ó ń dá ẹni kejì rẹ lẹ́jọ́?

Ka pipe ipin Jákọ́bù 4

Wo Jákọ́bù 4:12 ni o tọ