Jákọ́bù 4:14 BMY

14 Nígbà tí ẹ̀yin kò mọ ohun tí yóò hù lọ́la. Kí ni ẹ̀mí yín? Ìkuuku sáà ni yín, tí ó hàn nígbà díẹ̀, lẹ́yìn náà a sì túká lọ.

Ka pipe ipin Jákọ́bù 4

Wo Jákọ́bù 4:14 ni o tọ