Jákọ́bù 4:4 BMY

4 Ẹ̀yin panṣágà ọkùnrin, àti panságà obìnrin, ẹ kò mọ̀ pé ìbárẹ́ ayé ìṣọ̀tá Ọlọ́run ni? Nítorí náà ẹni tí ó bá fẹ́ láti jẹ́ ọ̀rẹ́ ayé di ọ̀ta Ọlọ́run.

Ka pipe ipin Jákọ́bù 4

Wo Jákọ́bù 4:4 ni o tọ