Jákọ́bù 4:9 BMY

9 Ẹ banújẹ́, ẹ sọ̀fọ̀, kí ẹ sì hu fún ẹkún. Ẹ jẹ́ kí ẹ̀rín yín kí ó di ọ̀fọ̀, àti ayọ̀ yín kí ó di ìbànújẹ́.

Ka pipe ipin Jákọ́bù 4

Wo Jákọ́bù 4:9 ni o tọ