Daniẹli 11:43 BM

43 Yóo di aláṣẹ lórí wúrà, fadaka ati àwọn nǹkan olówó iyebíye ilẹ̀ Ijipti; àwọn ará Libia ati Etiopia yóo máa tẹ̀lé e lẹ́yìn.

Ka pipe ipin Daniẹli 11

Wo Daniẹli 11:43 ni o tọ