Daniẹli 12:6 BM

6 Ọ̀kan ninu wọn bi ẹni tí ó wọ aṣọ funfun, tí ó wà lókè odò pé, “Nígbà wo ni àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tí ń bani lẹ́rù wọnyi yóo dópin?”

Ka pipe ipin Daniẹli 12

Wo Daniẹli 12:6 ni o tọ