Daniẹli 4:22 BM

22 “Ìwọ ọba ni igi yìí, ìwọ ni o dàgbà, tí o di igi ńlá, tí o sì lágbára. Òkìkí rẹ kàn dé ọ̀run, ìjọba rẹ sì kárí gbogbo ayé.

Ka pipe ipin Daniẹli 4

Wo Daniẹli 4:22 ni o tọ