Daniẹli 5:3 BM

3 Wọ́n bá kó àwọn ife wúrà ati ti fadaka tí wọ́n kó ninu tẹmpili ní Jerusalẹmu jáde, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí fi wọ́n mu ọtí.

Ka pipe ipin Daniẹli 5

Wo Daniẹli 5:3 ni o tọ