Daniẹli 6:14 BM

14 Nígbà tí ọba gbọ́ ọ̀rọ̀ yìí, ọkàn rẹ̀ dàrú lọpọlọpọ, ó sa gbogbo ipá rẹ̀ títí ilẹ̀ fi ṣú láti gba Daniẹli sílẹ̀.

Ka pipe ipin Daniẹli 6

Wo Daniẹli 6:14 ni o tọ