Daniẹli 6:5 BM

5 Wọ́n sọ fún ara wọn pé, “A kò ní rí ẹ̀sùn kà sí Daniẹli lẹ́sẹ̀, àfi ohun tí ó bá jẹmọ́ òfin Ọlọrun rẹ̀.”

Ka pipe ipin Daniẹli 6

Wo Daniẹli 6:5 ni o tọ