Daniẹli 6:8 BM

8 Nisinsinyii, kabiyesi, ẹ fi ọwọ́ sí òfin yìí, kí ó lè fi ìdí múlẹ̀, gẹ́gẹ́ bí òfin Mede ati Pasia tí kò gbọdọ̀ yipada.”

Ka pipe ipin Daniẹli 6

Wo Daniẹli 6:8 ni o tọ