Daniẹli 7:11 BM

11 “Mo wò yíká nítorí ọ̀rọ̀ ńláńlá tí ìwo kékeré yìí ń fi ẹnu sọ, mo sì rí i tí wọ́n pa ẹranko náà, tí wọ́n sì jó òkú rẹ̀ níná.

Ka pipe ipin Daniẹli 7

Wo Daniẹli 7:11 ni o tọ