Daniẹli 8:10 BM

10 Ó tóbi pupọ tóbẹ́ẹ̀ tí ó fi ń bá àwọn ogun ọ̀run jà, ó já àwọn kan ninu àwọn ìràwọ̀ lulẹ̀, ó sì fi ẹsẹ̀ tẹ̀ wọ́n mọ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Daniẹli 8

Wo Daniẹli 8:10 ni o tọ