Ẹkún Jeremaya 1:16 BM

16 “Nítorí àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ wọnyi ni mo ṣe sọkún;tí omijé ń dà lójú mi;olùtùnú jìnnà sí mi,kò sí ẹni tí ó lè dá mi lọ́kàn le.Àwọn ọmọ mi ti di aláìní,nítorí pé àwọn ọ̀tá ti borí wa.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremaya 1

Wo Ẹkún Jeremaya 1:16 ni o tọ