Ẹkún Jeremaya 1:17 BM

17 “Sioni na ọwọ́ rẹ̀ fún ìrànwọ́,Ṣugbọn kò sí ẹni tí ó ràn án lọ́wọ́,OLUWA ti pàṣẹ pé,kí àwọn aládùúgbò Jakọbu di ọ̀tá rẹ̀;Jerusalẹmu sì ti di eléèérí láàrin wọn.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremaya 1

Wo Ẹkún Jeremaya 1:17 ni o tọ