Ìwé Oníwàásù 1:13 BM

13 Mo fi tọkàntọkàn pinnu láti fi ọgbọ́n wádìí gbogbo ohun tí eniyan ń ṣe láyé.Làálàá lásán ni iṣẹ́ tí Ọlọrun fún ọmọ eniyan ṣe lórí ilẹ̀ ayé.

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 1

Wo Ìwé Oníwàásù 1:13 ni o tọ