Ìwé Oníwàásù 1:16 BM

16 Mo wí lọ́kàn ara mi pé, “Mo ti kọ́ ọpọlọpọ ọgbọ́n, ju gbogbo àwọn tí wọ́n ti jọba ní Jerusalẹmu ṣáájú mi lọ. Mo ní ọpọlọpọ ìrírí tí ó kún fún ọgbọ́n ati ìmọ̀.”

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 1

Wo Ìwé Oníwàásù 1:16 ni o tọ