Ìwé Oníwàásù 10:17 BM

17 Ilẹ̀ tí ọba rẹ̀ kì í bá ṣe ọmọ ẹrú ṣoríire!Tí àwọn olórí rẹ̀ ń ṣe àríyá ní àsìkò tí ó tọ́;tí wọn ń jẹ tí wọn ń mu kí wọn lè lágbára,ṣugbọn tí kì í ṣe fún ìmutípara.

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 10

Wo Ìwé Oníwàásù 10:17 ni o tọ