4 Bí aláṣẹ bá ń bínú sí ọ,má ṣe torí rẹ̀ kúrò ní ìdí iṣẹ́ rẹ,ìtẹríba lè mú kí wọn dárí ẹ̀ṣẹ̀ tí ó bá tóbi jini.
Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 10
Wo Ìwé Oníwàásù 10:4 ni o tọ