Ìwé Oníwàásù 10:6 BM

6 Wọ́n fi àwọn òmùgọ̀ sí ipò gíga, nígbà tí àwọn ọlọ́rọ̀ wà ní ipò tí ó rẹlẹ̀.

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 10

Wo Ìwé Oníwàásù 10:6 ni o tọ