1 Ranti ẹlẹ́dàá rẹ ní ìgbà èwe rẹ, kí ọjọ́ ibi tó dé, kí ọjọ́ ogbó rẹ tó súnmọ́ etílé, nígbà tí o óo wí pé, “N kò ní inú dídùn ninu wọn.”
Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 12
Wo Ìwé Oníwàásù 12:1 ni o tọ