9 Yàtọ̀ sí pé ọ̀jọ̀gbọ́n náà gbọ́n, ó tún kọ́ àwọn eniyan ní ìmọ̀. Ó wádìí àwọn òwe fínnífínní, ó sì tò wọ́n lẹ́sẹẹsẹ.
Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 12
Wo Ìwé Oníwàásù 12:9 ni o tọ