Ìwé Oníwàásù 2:23 BM

23 Nítorí gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀ kún fún ìrora, iṣẹ́ rẹ̀ sì jẹ́ ìbànújẹ́ fún un. Ọkàn rẹ̀ kì í balẹ̀ lóru, asán ni èyí pẹlu.

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 2

Wo Ìwé Oníwàásù 2:23 ni o tọ