Ìwé Oníwàásù 2:7 BM

7 Mo ra ọpọlọpọ ẹrukunrin ati ẹrubinrin, mo sì ní àwọn ọmọ ẹrú tí wọn bí ninu ilé mi, mo ní ọpọlọpọ agbo mààlúù ati agbo ẹran, ju àwọn tí wọ́n wà ní Jerusalẹmu ṣáájú mi lọ.

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 2

Wo Ìwé Oníwàásù 2:7 ni o tọ