20 Ibìkan náà ni gbogbo wọn ń lọ; inú erùpẹ̀ ni gbogbo wọn ti wá, inú erùpẹ̀ ni wọn yóo sì pada sí.
Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 3
Wo Ìwé Oníwàásù 3:20 ni o tọ